Skip to main content

Posts

Showing posts from September, 2022

Osun ni awon wa Obidient pelu irin afaralokun eyi ti awon omo ipinle Osun...

Gege bi orilede Nigeria se ma se ayeye igbominira ni ojo kinni osu kewa 1st October, awon omo ipinle Osun ati olugbe re loni nise lawon duro digbi pelu oludije si ipo aare orilede yi labe asia egbe oselu Labour Party iyen ogbeni Peter Obi pelu irin afaralokun eyi ti won gbekale lati mi ipinle Osun. Irin afaralokun ohun eyi ti yio gberaso lati freedom park Osogbo ni gbogbo awon ololufe Peter Obi ti setan lati tuyaya tuyaya jade fun ni ojo kinni osu kewa October 1st. Omo Oba Adeyeye Hafeez Adeola to je adari gbogbo ajo to n gbaruku ti wiwole Ogbeni Peter Obi losun iyen Osun UFPO loni ko si iye meji wipe gbogbo odo ati awon agbagba ipinle Osun ti setan lati dibo won fun Peter Obi fun aare orilede yi ni odun 2023. Ninu oro alaga to n dari gbogbo eto irin afaralokun na Ogbeni Muhydeen Mustapha loni gbogbo eto lo ti wa nile fun irin afaralokun na lati je aseyori eyi ti awon nreti awon eniyan lati gbogbo ijoba ibile Osun ati awon ilu miran to tun yato si ipinle Osun.

Kabiesi Olowu Kuta Alayeluwa Oba Hameed Adekunle Oyelude Makama Tegbosun III se ayeye odun mewa lori ite awon baba nla won nibi ti opo Oba alade, oloye ati

 Kabiesi Olowu Kuta Alayeluwa Oba Hameed Adekunle Oyelude Makama Tegbosun III se ayeye odun mewa lori ite awon baba nla won nibi ti opo Oba alade, oloye ati opo awon eyan peju sibe lati ba Kabiesi dawo idunnu. Ninu oro ti awon eniyan ba Oniroyin Kijipa TV so ni wioe asiko Kabiesi Makama tun ilu lara pupo. Won ni ni alafo odun mewa ti Kabiesi gori ite baba won, orisirisi idagbasoke alailegbe  ni won ti mu wo ilu Kuta ti gbogbo awon eniyan si n gba ladura wipe opo odun ni Kabiesi yio se lori apere awon baba nla won. Kabiesi Alayeluwa Oba Hameed Adekunle Oyelude Makama Tegbosun III, Olowu of Owu Kuta, ki epe bi mope se n pe, ki e dagba, ke gbo kujokujo lori apere awon baba nla yin.