Skip to main content

BI A SE N JADE LATI LO DIBO, MA SE TA IBO E TORI KI IYA ODUN MERIN MIRAN MA JE YIN

 Bi gbogbo eyin omo ipinle Osun se n jade lati lo dibo yan oludari tuntun loni, mo ro yin lati yago fun tita ibo yin. Asiko ni yi fun yin lati tun so bi odun merin yin miran tun se ma ri. Oro yi lo jade lenu oludibo si ipo gomina ipinle Osun labe asia egbe African Action Congress AAC Ogbeni Olufemi Eniolapo Johnson.

Ninu oro re, o ni awon ti gbaradi fun ohun gbogbo to lewu ko sele loni ninu eto idibo na. O ni bi egbe oselu kankan ba gbiyanju lati ra ibo abi wu iwa ko to kankan loni, awon yo si won lona ti won ko lero rara tori awon o ni laju kale ki won o tun je awon omo ipinle yi mo aye fun odun merin miran. O ni ki onile o gbo, ko so fun toko, ko ni si aye magomago kankan loni tori wipe awon na ti mura won sile.

O ni awon o ni ra ibo be si ni awon omo egbe awon o ni ta ibo won fun enikeni. Ipinle Osun, ti gbogbo wa ni tori eyi a gbodo dibo bo ti to ati bo ti ye.


Comments

Popular posts from this blog

Osun ni awon wa Obidient pelu irin afaralokun eyi ti awon omo ipinle Osun...

Gege bi orilede Nigeria se ma se ayeye igbominira ni ojo kinni osu kewa 1st October, awon omo ipinle Osun ati olugbe re loni nise lawon duro digbi pelu oludije si ipo aare orilede yi labe asia egbe oselu Labour Party iyen ogbeni Peter Obi pelu irin afaralokun eyi ti won gbekale lati mi ipinle Osun. Irin afaralokun ohun eyi ti yio gberaso lati freedom park Osogbo ni gbogbo awon ololufe Peter Obi ti setan lati tuyaya tuyaya jade fun ni ojo kinni osu kewa October 1st. Omo Oba Adeyeye Hafeez Adeola to je adari gbogbo ajo to n gbaruku ti wiwole Ogbeni Peter Obi losun iyen Osun UFPO loni ko si iye meji wipe gbogbo odo ati awon agbagba ipinle Osun ti setan lati dibo won fun Peter Obi fun aare orilede yi ni odun 2023. Ninu oro alaga to n dari gbogbo eto irin afaralokun na Ogbeni Muhydeen Mustapha loni gbogbo eto lo ti wa nile fun irin afaralokun na lati je aseyori eyi ti awon nreti awon eniyan lati gbogbo ijoba ibile Osun ati awon ilu miran to tun yato si ipinle Osun.

Ẹ yé kọ ohùn tí kò dára nípa orílè-èdè Nigeria mọ ẹyin o ní ìwé ìròyìn torí bí o ni gba ba ṣe pé igba rẹ na ní wọn a ṣe bá pe

Ẹ yé kọ ohùn tí kò dára nípa orílè-èdè Nigeria mọ ẹyin o ní ìwé ìròyìn torí bí o ni gba ba ṣe pé igba rẹ na ní wọn a ṣe bá pe Kabiesi Alayeluwa Oba Hameed Adekunle Oyelude MAKAMA CON Olowu ti Owu Kuta ni wọn tí rọ àwọn oníròyìn láti maá fí gege wọn kọ ohùn búburú nípa orílè-èdè Nigeria mọ torí wípé ko ní ànfààní kánkan tí yíó ṣe fún wa o. Ninu ọrọ Oba alaye ohùn ní wọn tí ní kó sí orile-ede tí kò ní kudiẹ kudiẹ tí e sugbon ọgbọn ní wọn fi n to. Wọn ní kí àwọn oníròyìn yé tí torí owo gba abode fún orilede yí torí bí o ni gba ba ṣe pé igba rẹ na ní àwọn èèyàn yio se bá pé. Ọrọ yi lo jẹ jáde ní igba tí oniroyin ile iṣẹ wa ni Kijipa TV n ṣe iforowero pelu Oba Aládé ohun latari àmì ẹ̀yẹ orilede yi CON ti aare ana Muhammadu Buhari fí da wọn lọla. https://youtu.be/TI_wnE2byw0 Oba Olowu Kuta ninu ọrọ wọn bakanna ṣe ileri láti túbọ̀ má gbaruku ti awọn ọdọ ni ilu awọn ati lorilede yi bí àwọn ti ṣe má n ṣe tẹlẹ. Kabiesi wá dupẹ lọwọ gbogbo awọn ènìyàn tó bá wọn dawọ ìdùnnú pẹlu àmì ẹ̀yẹ na pápá j

Osun 2022, Ko si ohùn tí ẹgbẹ Oṣelu APC àti PDP ní fún àwọn ọmọ ìpínlè Òsun - ọmọ ọba Adeola Adeyeye.

  Osun 2022, Ko si ohùn tí ẹgbẹ Oṣelu APC àti PDP ní fún àwọn ọmọ ìpínlè Òsun - ọmọ ọba Adeola Adeyeye. Ọmọ Ọba Hafeez Adeola Adeyeye to je alukoro ẹgbẹ New Nigeria People's Party (NNPP) tí sọ nínú ọrọ rẹ fún àwọn oníròyìn wípé kòsí nkan gidi kan tí ẹgbẹ Oṣelu APC àti PDP ní fún àwọn ọmọ ìpínlè Òsun. O ní àwọn ẹgbẹ mejeji ni wọn tí tuko iṣẹ ìjọba ìpínlè Òsun tí a sì ti rí ohùn tí wọn ṣe ati ohun ti wọn le se. Ìjọba tí o bá lè fi ebi pa awọn ọmọ ìlú rẹ o ni nkan gidi tí o le ṣe fún wọn. O wa ro gbogbo ọmọ ìpínlè Òsun láti fojú silẹ dibo fún ẹni tí yíó fún wọn ní ìgbé ayé irorun yatọ sí àwọn tí yíó fí ohunje ti o to nkan àti ẹgbẹrun kàn naira(₦1,000) tá n wọn láti tún jẹ wọn mọ ayé fún ọdún mẹrin míràn.