Ẹ yé kọ ohùn tí kò dára nípa orílè-èdè Nigeria mọ ẹyin o ní ìwé ìròyìn torí bí o ni gba ba ṣe pé igba rẹ na ní wọn a ṣe bá pe Kabiesi Alayeluwa Oba Hameed Adekunle Oyelude MAKAMA CON Olowu ti Owu Kuta ni wọn tí rọ àwọn oníròyìn láti maá fí gege wọn kọ ohùn búburú nípa orílè-èdè Nigeria mọ torí wípé ko ní ànfààní kánkan tí yíó ṣe fún wa o. Ninu ọrọ Oba alaye ohùn ní wọn tí ní kó sí orile-ede tí kò ní kudiẹ kudiẹ tí e sugbon ọgbọn ní wọn fi n to. Wọn ní kí àwọn oníròyìn yé tí torí owo gba abode fún orilede yí torí bí o ni gba ba ṣe pé igba rẹ na ní àwọn èèyàn yio se bá pé. Ọrọ yi lo jẹ jáde ní igba tí oniroyin ile iṣẹ wa ni Kijipa TV n ṣe iforowero pelu Oba Aládé ohun latari àmì ẹ̀yẹ orilede yi CON ti aare ana Muhammadu Buhari fí da wọn lọla. https://youtu.be/TI_wnE2byw0 Oba Olowu Kuta ninu ọrọ wọn bakanna ṣe ileri láti túbọ̀ má gbaruku ti awọn ọdọ ni ilu awọn ati lorilede yi bí àwọn ti ṣe má n ṣe tẹlẹ. Kabiesi wá dupẹ lọwọ gbogbo awọn ènìyàn tó bá wọn dawọ ìdùnnú pẹlu àmì ẹ̀yẹ na pápá j
Gege bi orilede Nigeria se ma se ayeye igbominira ni ojo kinni osu kewa 1st October, awon omo ipinle Osun ati olugbe re loni nise lawon duro digbi pelu oludije si ipo aare orilede yi labe asia egbe oselu Labour Party iyen ogbeni Peter Obi pelu irin afaralokun eyi ti won gbekale lati mi ipinle Osun. Irin afaralokun ohun eyi ti yio gberaso lati freedom park Osogbo ni gbogbo awon ololufe Peter Obi ti setan lati tuyaya tuyaya jade fun ni ojo kinni osu kewa October 1st. Omo Oba Adeyeye Hafeez Adeola to je adari gbogbo ajo to n gbaruku ti wiwole Ogbeni Peter Obi losun iyen Osun UFPO loni ko si iye meji wipe gbogbo odo ati awon agbagba ipinle Osun ti setan lati dibo won fun Peter Obi fun aare orilede yi ni odun 2023. Ninu oro alaga to n dari gbogbo eto irin afaralokun na Ogbeni Muhydeen Mustapha loni gbogbo eto lo ti wa nile fun irin afaralokun na lati je aseyori eyi ti awon nreti awon eniyan lati gbogbo ijoba ibile Osun ati awon ilu miran to tun yato si ipinle Osun.